Alimosho (Live)-文本歌词

Alimosho (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Mi ò ì f’érò lórí Stage yìí ẹ jọ̀ọ́ nítorí Ọlọ́run o

(Kábi ọ ò sí)

Ó da k’énìyàn kó ní respect

Wọ́n ní àwọn Ọba aládé ń jó lọ́wọ́

Kí ló ná wa, bí a bá fún wọn láàyè, ká jẹ́ wọ́n ó jó

Talazo Wese

(Igi jẹ́gẹ́dẹ́, ẹ bá mi k’Áyìndé, Bàbá Sawatu Arafa)

Bàbá t’Àkànkẹ́ Melisa (arábámbí)

Bàbá Àkànkẹ́ Melisa (arábámbí)

Adébọ̀sípò (arábámbí)

Ọmọ mi Àkànkẹ́ Melisa (arábámbí)

Talazo Wese

(Igi jẹ́gẹ́dẹ́, ẹ bá mi k’Áyìndé, Bàbá Sawatu Arafa)

Ọjọ́ tí a ti ń wá’bí

Níṣe là ń mu lẹ́sẹsẹ o, là ń mu lẹ́sẹsẹ

Àwọn political leaders ní gbogbo Alimosho

Alimosho lápapọ̀ pátápátá

Gbogbo yín ni mo kí

Honorable Bisi Yusuf, honorable Fẹ́mi o member house if representative

Ẹ sọ fún àwọn Ọlọ́pàá, wọ́n ti yin tear gas

Alimosho, kì í ṣe ibi tí wọ́n ti ń ṣe káti káti kí ló wá ti jẹ́?

Ẹ̀yin àgbà tó ń bẹ níbẹ̀, ẹ yẹ Ibẹ̀ wo Ọmọ́gbọ́láhàn arábámbí Ọba orin

Tọ́lání, kí ló ṣẹlẹ̀? Security Committee

Chair Security Committee, ẹ yẹ Ibẹ̀ wo Kílóṣẹlẹ̀?

Kò ṣẹlẹ̀ rí l’Alimodho, ẹ má ba fàájì jẹ́ o

Ijó dijó àwọn political leaders, honorable Fẹ́mi o member house of representatives,

Honorable Bisi Yusuf, house of assembly

Abudullahi ẹnílọlóbọ̀, Lagos State Apex leader

Honorable Usamat Shehu, Honourable Commissioner for youth and Social Development

Sister Temi Ọmọ́gbọ́láhàn arábámbí Ọba orin, ‘ṣagbọlá mi ọ̀gọjì

Honorable Isah Yusuf Alhaji, Honourable Bisi, Bísí Adébajò

Honourable Prince Dàpọ̀ ọmọ Adébàjò

Pẹ̀lú woman leader ẹgbẹ́ wa o, woman leader ẹgbẹ́ wa

Chief Mrs Kẹ́mi Nelson mi

Ẹ̀yin political leaders Ijó yá àti Alhaji Tajudeen mi Àgbẹ̀dẹ Badiru

Mo kí ẹ kí ẹ ọmọ Àgbẹ̀dẹ