wà àgbà (Live)-文本歌词

wà àgbà (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Yusufu, ẹ máa bá mi tọ́jú àwọn bàbá Àdìmúlà

Arẹ́gbẹ́ṣọlá mi Raufu

Raufu kí ẹ bá mi ki, owó bàbá Kabiru

Kò ní bàjẹ́ fún ẹgbẹ́ wa àmín

Kò le è bàjẹ́ o, ni gbogbo Alimosho

Ni wọ́n fi pa’hun pọ̀, ni wọ́n ṣe ìkan ṣoṣo

(Kò le è bàjẹ́ o)

Bísí Bísí, bo bá mú sùúrù

(ó ṣì máa dára lọ́lá Ọlọ́hun)

Bó ṣe ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ yìí

Torí gvèjò gvèjò tó bá ní sùúrù, á mú garawa lọ́jọ́ọ̀jọ́kan àfàìrọ̀ òjò

Abbey, ó ní Òun wá náwó, owó ẹnílọlóbọ̀

Abbey, ó lówó ẹnilọlóbọ̀ ló ń ná

Ó wá náwó leader, Abbey ọmọ Èjígbádéró

Èjígbádéró mi Abbey, ó lówó leader lòun ń ná

Ẹnilọlóbọ̀ Àyìndé adé

Ọmọ l’Àyìndé o, ọmọ l’Àyìndé o

Abdullahi mi káre Àyìndé o

(Ọmọ l’Àyìndé o)

ọmọ l’Àyìndé o

Abdullahi mi kì í kan ò ní ṣe ẹ́

(Ọmọ l’Àyìndé o)

Abudulahi, Abbey ó ṣá ni ń máa kími, kí n máa kẹ

Àna Èjígbádéró

Ìwà mà ni ẹ wò Abudulahi, Ìwà mà ni ẹ wò

Bó o bá j’ohun gbé o, kó o má j’ohùn gbé o

Ìwà mà ni ẹ wò Abudulahi

(Ìwà mà ni ẹ wò , Ìwà mà ni ẹ wò)

(Ẹnílọlóbọ̀, Bó o bá j’ohun gbé o, kó o má j’ohùn gbé o)

(Ìwà mà ni ẹ wò )

Ìwà ni Abudulahi mi ló fi ṣe é

Ọmọ Ẹnílọlóbọ̀, wọ́n ní ọmọdé yìí jù ẹ́ lọ, o nií bíntín

Ṣé ìyẹn ṣe é fé kúrò níbẹ̀, o jẹ́ gbà fún Ọlọ́hun Ọba

Ìwà mà ni ẹ wò ọjọ́ orí kọ́ , Ìwà mà ni ẹ wò

Bó o bá j’ohun gbé o, kó o má j’ohùn gbé o

Ìwà mà ni ẹ wò

(Ìwà mà ni ẹ wò , Ìwà mà ni ẹ wò, Abdullahi )

(Ọmọ Ẹnílọlóbọ̀, Bó o bá j’ohun gbé o, kó o má j’ohùn gbé o)

(Ìwà mà ni ẹ wò )

Abudulahi (Abudulahi mi)

Abudulahi (Abudulahi mi)

Abudulahi (Abudulahi mi)

Ó ti kékeré jẹ leader (Ẹ bá mi kí Àyìndé)

Ẹ bámi kí Àyìn’ (Ẹ bámi kí Àyìndé)

Ó ti kékeré jẹ leader (Ẹ bá mi kí Àyìndé)

Àyìndé, kò le bàjẹ́ o

Bó di kànràn kó bàjẹ́ o, kí ọ̀tá lè máa yọ̀ Àyìndé

(Kò le è bàjẹ́ o)

Baby tó wọ skimpy yìí (ìwọ là ń kí)