dún Baby (Live)-文本歌词

dún Baby (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Ọdún Baby, o kú iléde bàbá ẹ

Aya Ganiyu Adébáyọ̀ mi Quadri yìí ọdún o

Ọdún ọmọ Ọ̀rẹ́dẹ̀yìn mi

Risikiyatu máa gbọ́

Ọdún aya Quadri, aya Abdulganiyu

Ọmọ oní Mushin ànádòru o

Aya wọn ní’jẹ̀bú Mushin Ọdún, aya òní Mushin ànákòru

Ọdún ṣá ni life wire Abdulganiyu

Ọmọ oní Mushin àjíná

Ọlábísí, Ọdún baby mi Lábísí

Lábísí ó ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Lábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ o

Ọlábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Èèyàn tí ò dùn mọ́ o kó jẹ soda m’ẹ́bà

(Lábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ)

Ọdún Lábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Aya t’Abdulganiyu Olúmidé

Ọlábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Èèyàn tí ò dùn mọ́ o kó jẹ soda m’ẹ́bà

(Lábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ)

Olúmidé ọmọ Akínsànyà ọkọ Lynda

Ó ní Lábísí o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Ọdún baby o ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Bí a rí ẹni tí ò dùn mọ̀ o kó jẹ soda m’ẹ́bà

(Ọlábísí ò ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ)

Awo Tinúkẹ́ Mádójútìmí

Awo Lọlá, ìyẹn Lọlá Ondo

Awo Bùnmi ọmọbuwà yìí o ṣé

Awo Doyin Adémilúyì

Awo Àdùnní 50 yìí o ṣé

Beauty baby, awo Bùnmi ọmọbuwà

Ọmọbuwà Bùnmi

Awo Lọlá Ondo, mowànínúọlá lọlá mi l’Ondo ilé

Excellent, mò ń bọ̀ wá torí Ọlọ́hun Àyìndé

Aya t’Abdulrasheed ọmọ gbélébùwà

Lọlá aya wa ní’jẹ̀bú òde, Lọlá mi sweetie

Awo Bùnmi Ọmọbuwà ọmọbuwà Bùnmi

Ọdún Lábísí, Lábísí Ọ̀rẹ́dẹ̀yìn aya t’Abdulganiyu

Aya Ganiyu Quadri mi Ọdún

Life wire Quadri yìí o káre sweetie Ọlábísí

Lábísí ò ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ

Èèyàn tí ò dùn kọ́ o, kó jẹ soda m’ẹ́bà

(Lábísí ò ti b’ọ́kọ ẹ̀ lọ)

Lábísí baby (Lábísí baby)

Lábísí baby (Lábísí baby)

Lábísí baby (Lábísí baby)

Ọdún Ọlábísí baby (Ọlábísí baby)

Ọdúnọlá Lábísí Ọ̀rẹ́dẹ̀yìn (Ọlábísí baby)

Aya Ganiyu Quadri (Ọlábísí baby)

Aya t’a Débáyọ̀ Quadri (Ọlábísí baby)

Aya òní Mushin àjíná, life wire Adébáyọ̀ Quadri

(Lábísí baby)

Lábísí baby (Ọlábísí baby)

Lábísí baby (Lábísí baby)

Lábísí baby (Lábísí baby)

Ọdún ọmọ Ọ̀rẹ́dẹ̀yìn (Lábísí baby)

Odò ti gbé oníyẹ̀yẹ́ lọ

(Kò wa tán, ẹni bá wù kó jẹ soda kó máa b’ómi lọ)

Odò ti gbé oníyẹ̀yẹ́ lọ o

(Kò wa tán, ẹni bá wù kó jẹ soda kó máa b’ómi lọ)

Torí pé èyí o (ní western Fújì o, èyí o ni western Fújì)

Àyìndé arábámbí, lawyer Ṣófọlá

Barrister lawyer ọmọ Ṣófọlá torí Ọdún

Ọdún ọmọ Ọ̀rẹ́dẹ̀yìn Ọlábísí